sọgbódilé sọ̀gbẹ́dìgboro noun /sɔ̄.ɡ͡bó.dī.lé sɔ̀.ɡ͡bɛ́.dì.ɡ͡bō.ɾō/
sọgbódilé-sọ̀gbẹ́dìgboro (alternative), sọgbó-dilé sọ̀gbẹ́-dìgboro (alternative)
Definitions
  1. development (in rural areas or at the fringes of urban areas); urban sprawl
    Àtẹ̀jáde kan tí Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè fi ṣọwọ́ sáwọn oníròyìn sọ pé: “Nítorí iṣẹ́ àgbẹ̀, iṣẹ́ sọgbódilé-sọ̀gbẹ́dìgboro àtàwọn ìgbòkègbodò míì téèyàn ò lè tètè rí ipa wọn, àwọn igbó kìjikìji tó kù sórí àwọn òkè kan ti ń pa run.” “Some of these last wild areas are fast disappearing in the face of agriculture, infrastructure development and other creeping impacts,” explains a recent United Nations press release.
Etymology
From the phrase "sọgbó dilé sọ̀gbẹ́ dìgboro, ọba asààtàn dọjà", an oríkì for a successful ọba that maintains and expands a settlement, ultimately from sọ (“to make”) + igbó (“forest”) + di (“to become”) + ilé (“house”) + sọ (“to make”) + ìgbẹ́ (“bush”) + di (“to become”) + ìgboro (“urban area”), literally “[the process which] turns forests into homes and bush into towns.”.
Component words
Source: Wiktionary, where this word is spelled “sọgbodile sọgbẹdigboro”. Reference: en-sọgbodile_sọgbẹdigboro-yo-noun-FMPI5uyB