ọkàn noun /ɔ̄.kã̀/
ọkọ̀n (alternative)
Definitions
  1. physical heart
    Ọkàn rẹ̀ ń lù pupuupu. Her heart was beating very quickly.
    Àrùn ọkàn ń dààmú-un wọn. They were suffering [from] a heart disease.
  2. mind, psychological heart
    Mo ní in lọ́kàn pé mo máa lọ sí Ìbàdàn láti rí ọ̀rẹ́ mi. I had it in mind that I would go to Ibadan to see my friend.
    Ẹ̀rí ọkàn yóò máà jẹ́ wọn lọ títí láé. Their conscience will continue to prick them forever.
  3. bravery
    Ọkùnrin yìí lọ́kàn láti dúró de ẹkùn This man was courageous to have stood in the way of a tiger.
  4. thought
    Ọkàn gbọgbẹ́ To be very depressed
    Ọkàn mi wà ní ibòmíràn. My thoughts are elsewhere.
Etymology
Likely a Proto-Yoruba innovation that displaced ẹ̀dọ̀ (“chest, heart, emotion”), which served as the term for the organ for the seat of emotion (heart). In Northwest Yoruba and Standard Yoruba, this term semantically shifted to "liver," while certain Yoruba dialects maintain the semantic meaning of ẹ̀dọ̀ "emotion, feeling." However, almost all Yoruba dialects refer to the heart organ as "ọkàn," suggesting that it was a Proto-Yoruba innovation, see Proto-Yoruba *ɔ-kã̀, with it likely not existing in Proto-Edekiri. Yoruba dialects like Southeast Yoruba not descended from Proto-Yoruba likely thus borrowed the word from nearby Proto-Yoruba speakers. Evidence of pre-Yoruba roots may be found in a possible cognate, Olukumi akan (“kidney”), suggesting the term may have been a general root for internal organs, in a similar fashion to the word fùkù.
Dialectal synonyms “heart” 31 varieties

Southeast Yoruba

Ìjẹ̀bú Òde
ọkọ̀n
Ẹ̀pẹ́
ọkọ̀n
Ìkòròdú
ọkọ̀n
Ṣágámù
ọkọ̀n

Ìtsẹkírì

Ìwẹrẹ
ẹ̀dọ̀nọdùdù

Olùkùmi

Ugbódù
íghórẹ̀dọ̀

Northwest Yoruba

Ìjàká
ọkàn
Òtù
ọkẹ̀n
Ìwéré Ilé
ọkẹ̀n
Òkèhò
ọkàn
Ìsẹ́yìn
ọkẹ̀n
Ṣakí
ọkẹ̀n
Tedé
ọkẹ̀n
Ìgbẹ́tì
ọkẹ̀n
Ọ̀yọ́
ọkàn
Nàìjíríà
ọkàn
Bɛ̀nɛ̀
ɔkàn

Northeast Yoruba/Okun

Kabba
ọkọ̀nẹ̀kẹ̀dọ̀

Ede languages/Southwest Yoruba

Cábɛ̀ɛ́ (Ìdàdú)
ɔkɛ̀n
Tchaourou
ɔkɛ̀n
Baàtɛ
ɔkàn
Igbó Ìdàácà (Dasa Zunmɛ̀)
ɔkàn
Ìkpòbɛ́
emí
Onigbolo
ɔkàn
Kétu
ɔkàn
Akpáré
owũ̀
Atakpamɛ
owũ̀
Boko
owũ̀
Moretan
owũ̀
Tchetti (Tsɛti, Cɛti)
oŋù ɛ̀ɖɔ̃̀
Kandi
ímũ
View the dialect map on Wiktionary ↗
Used in
Source: Wiktionary · etymology 3, where this word is spelled “ọkan”. Reference: en-ọkan-yo-noun-OowwC5zp