sun verb /sũ̄/ spelling unconfirmed
Definitions
  1. to roast
    Mo sun ẹran. I roasted the meat.
  2. to burn; to set on fire
    A máa ń sun òkú nínú àṣà tèmi. We cremate the dead in my culture.
    Àwọn jagunjagun ya wọ̀lú, wọ́n sì dáná sun ojúbọ The warriors raided the town and set the shrines on fire
Other entries with this spelling
Wiktionary records 3 entries spelled “sun”. You're reading one of them; here are the others.
Dialectal synonyms “to roast, burn” 18 varieties

Southeast Yoruba

Ìjẹ̀bú Òde
su
Ẹ̀pẹ́
su
Ìkòròdú
su
Ṣágámù
su
Òkìtìpupa
họn
Usẹn
họn

Olùkùmi

Ugbódù
họ́n

Central Yoruba

Àdó Èkìtì
sụn
Àkúrẹ́
sụn
Ọ̀tùn Èkìtì
sụn

Northwest Yoruba

Èbúté Mẹ́tà
sun
Èkó
sun
Ìbàdàn
sun
Ìlọrin
sun
Ọ̀yọ́
sun
Nàìjíríà
sun
Bɛ̀nɛ̀
sun

Northeast Yoruba/Okun

Kabba
hun
View the dialect map on Wiktionary ↗
Used in
àsunnoundáná sunìdánásungbóìdánásunlésísun
Possibly used in
Source: Wiktionary · etymology 2, where this word is spelled “sun”. Reference: en-sun-yo-verb-yo:to_roast