pọtimáńtò
noun
/k͡pɔ̄.tī.má.ŋ́.tò/
Definitions
-
suitcase
Bi Falọrọ ti wi niyẹn. Maneja ileeṣẹ naa paapaa, Nazih Tabet, nigba ti oun naa n jẹrii niwaju awọn adajọ sọ pe oun ati Falọrọ lawọn jọ ka owo naa, ti awọn si fi i sinu pọtimanto kan, pe ki wọn le lọọ ko owo naa si Backlays Bank, to wa ni Ọba Akran, n’Ikẹja.
Etymology
Borrowed from English portmanteau.
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “pọtimanto”.
Reference:
en-pọtimanto-yo-noun-mBemQWfl