pín verb /k͡pĩ́/
Definitions
  1. to divide
    O fẹ́ tọ́ ọ wò àbí? Màá pín in sí méjì. Do you want to taste it? I'll divide it in two.
  2. to share out; to distribute
    Àwọn apẹja pín èyí tí wọ́n pa fún gbogbo abúlé The fishermen shared their catch with the village
Etymology
Cognate with Igala kpẹ́
Used in
Source: Wiktionary · etymology 2, where this word is spelled “pin”. Reference: en-pin-yo-verb-dJhTD84U