ọ̀rọ̀-ìṣe
noun
/ɔ̀.ɾɔ̀.ì.ʃē/
IS (alternative), ọ̀rọ̀ ìṣe (alternative)
Definitions
-
verb
Kí ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Gẹ̀ẹ́sí "to meet"? What is the meaning of the English verb, "to meet"?Oriṣìí Ọ̀rọ̀-ìṣe (Verb Types) Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe (verb) mẹ́ta ni ó wà. Àwọn náà ni aláìgbàbọ̀ (intransitive), asopọ̀ (linking) àti agbàbọ̀ (transitive). Verb Types There are three types of verbs. They are intransitive verbs, linking verbs, and transitive verbs.Inú ọ̀rọ̀ ìṣe èdè Hébérù tó túmọ̀ sí “láti di” ni orúkọ náà, Jèhófà ti wá. The name Jehovah comes from a Hebrew verb that means “to become.”
Etymology
From ọ̀rọ̀ (“word”) + ìṣe (“action”), literally “action word”.
Used in
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “ọrọ-iṣe”.
Reference:
en-ọrọ-iṣe-yo-noun-aAb4ahfw