ọdún noun /ɔ̄.dṹ/
Definitions
  1. year
    ọdún ó yabo o! May the year be a favorable one!
  2. festival, festivity, celebration, holiday
    wọ́n máa ń ṣe ọdún Igogo nílùú Ọ̀wọ̀ lọ́dọọdún láti ṣe ìrántí òrìṣà Ọ̀rọnṣẹ̀n tó jẹ́ aya Ọlọ́wọ̀ Rẹ̀nrẹ̀ngẹnjẹ̀n nígbà ìwásẹ̀ They hold the Igogo festival every year in remembrance of the deity Oronsen, who was the wife of King Renrengenjen in the past
Etymology
Cognate with Ifè ɔɖɔ̃́, Igala ọ́dọ́ and Itsekiri ọdọ́n, proposed to derive from Proto-Yoruboid *ɔ-dʊ̃́
Used in
Abíọ́dúnnameàjọ̀dúnnounàtọdúnmọ́dúnbọ́dún ṣe ń gorí ọdúnẹ̀wádúnnounFálọdúnnamekú ọdún Kérésìmesì!intjkú ọdún tuntunintjlọ́dúnoríkádúnnounọdọọdúnnounọdún Agẹmọọdún Àjíǹdeọdún aléjọ́ọdún Egúngúnọdún Igogonameọdún Ìjẹṣunameọdún Kérésìmesìọdún oníbẹbẹọdún Oríkádúnọdún Ọlọ́jọ́nameọdún Ọ̀ṣun-Òṣogbonameọdún Ṣàngóọlọ́dún
Source: Wiktionary · etymology 2, where this word is spelled “ọdun”. Reference: en-ọdun-yo-noun-TLTqJVg8