òdo num /ò.dō/
òfo (alternative)
Definitions
  1. zero
    Òdo ni wọ́n gbá nínú ìdánwó yẹn. They got a zero on that test.
    Ni ọjọ Aje ni orilẹede Canada ti kọkọ [na] orilẹede [Cayman] Islands pẹlu ami ayo mọkanla si odo. On Monday, Canada first beat the Cayman Islands with a score of eleven to zero.
Other entries with this spelling
Wiktionary records 2 entries spelled “òdo”. You're reading one of them; here are the others.
Etymology
Probable cognate with Igala òfo (“zero”) and related to òfo (“empty, nothing, loss”)
Used in
Source: Wiktionary · etymology 1, where this word is spelled “odo”. Reference: en-odo-yo-num--RlOc~np