odó noun /ō.dó/
Definitions
  1. pounding mortar
    Níbo ni àwọn odó tí a máa ń lò láti gún iyán?. Where are the pounding mortars that we use to pound yam?
    Wọ́n ń gún iyán nínú odó. They were pounding pounded yam food in a pounding mortar.
Etymology
Cognate with Igbo odō and Edo odó, equivalent to o- (“nominalizing prefix”) + dó (“to pound”)
Component words
o-nominalizing prefix to pound
Used in
Source: Wiktionary · etymology 7, where this word is spelled “odo”. Reference: en-odo-yo-noun-LeATR1z1