ọ̀bọ noun /ɔ̀.bɔ̄/
Definitions
  1. monkey
    Ọ̀bọ mẹ́tàléláàádóje (133) ni ó wà nínú ọgbà ẹranko yìí. There are 133 monkeys in this zoo.
    Kò sí ohun tí ìnàkí fi ṣe orí tí ọ̀bọ kò fi ṣe orí. A baboon or chimpanzee's head is not different from a monkey's head. (proverb on equality)
  2. fool
    Ọ̀bọ ni wọ́n. They're fools.
    Ọlọ́run nìkan ṣoṣo l'ó gbọ́n, ọ̀bọ lènìyàn. It is only God who is wise, a human creature is a fool. (proverb on divine wisdom)
Etymology
Compare with Ibibio ebọk
Used in
Related terms
Source: Wiktionary · etymology 2, where this word is spelled “ọbọ”. Reference: en-ọbọ-yo-noun-AAwoVFf8