mu verb /mũ̄/ spelling unconfirmed
Definitions
  1. to drink
    Má mu ọtí tó o bá fẹ́ wakọ̀. Don't drink alcohol if you want to drive.
  2. to suck
    Ọmọ-ọwọ́ ṣì ń mu ọmú. The baby is still sucking breast.
  3. to lick (juicy fruits such as oranges, or deserts such as ice cream)
    Ọmọdé ń mu ọsàn. The child is licking orange.
  4. to smoke
    Kò kí ń mu sìgá. She doesn't smoke cigarettes.
Dialectal synonyms “to drink, suck, smoke” 37 varieties

Southeast Yoruba

Òkìtìpupa
mọ
Ọ̀wọ̀ (Ọ̀ghọ̀)
mọ

Ìtsẹkírì

Ìwẹrẹ
mọ

Olùkùmi

Ugbódù
mọ

Central Yoruba

Àdó Èkìtì
mụ
Àkúrẹ́
mụ
Ọ̀tùn Èkìtì
mụ

Northwest Yoruba

Èbúté Mẹ́tà
mu
Abẹ́òkúta
mu
Ìjàká
mọ
Èkó
mu
Ìbàdàn
mu
Ìlọrin
mu
Ọ̀yọ́
mu
Nàìjíríà
mu
Bɛ̀nɛ̀
mu

Northeast Yoruba/Okun

Ìsánlú Ìtẹ̀dó
mu
Kabba
mu

Ede languages/Southwest Yoruba

Sokode
mɔ
Cábɛ̀ɛ́ (Ìdàdú)
mɔ
Tchaourou
mɔ
Baàtɛ
mɔ
Igbó Ìdàácà (Dasa Zunmɛ̀)
mu
Ìkpòbɛ́
mɔ
Onigbolo
mɔ
Kétu
mu
Akpáré
mɔ
Atakpamɛ
mɔ
Boko
mɔ
Moretan
mɔ
Tchetti (Tsɛti, Cɛti)
mɔ
Aledjo-Koura
mɔ
Awotébi
mɔ
Partago
mɔ
Kandi
mɔ
Kambole
mɔ
Manigri
mɔ
View the dialect map on Wiktionary ↗
Used in
ajẹ-òkúta-má-mu-omiàmukùnounẹmunounfàmuverbmímu momiverb momiverb mọtímugbóverbmutíverbọmúnoun
Source: Wiktionary · etymology 1, where this word is spelled “mu”. Reference: en-mu-yo-verb-5i9kA2DY