ìfojú-máàsì-wò
noun
/ì.fō.d͡ʒú.máà.sì.wò/
Definitions
-
Marxism
Ohun tí Módù Karùn-ún yìí dálé ni tíọ́rì tàbí ìlànà ìfojú-máàsì-wò lítíréṣọ̀. Nínú ìdánilẹ́kọ̀ó tó wà ní módù yìí, ìwọ yóò ka nípa tíọ́rì yìí, ẹni tó dá tíọ́rì yìí sílẹ̀, àwọn agbátẹrù rẹ̀, ohun tó jẹ́ àfojúsùn tíọ́rì yìí pẹ̀lú àǹfàní (ire) àti àléébù (ibi) rẹ̀ fún iṣẹ́ lámèyítọ́. What Module 5 hinges upon is Marxist theory or said literary approach. In this module's lectures, you will read about the theory, the person who created it, its staunch supporters, what its focus is, along with its advantages (good) and its deficiencies (evil) for critical work.
Etymology
From ìfojú (“the act of using one's eyes”) + Máàsì (“Marx”) + wò (“to see”).
Component words
ìfojú<t:the act of using one's eyes>Máàsì<t:Marx>wò<t:to see>
Derived from
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “ifoju-maasi-wo”.
Reference:
en-ifoju-maasi-wo-yo-noun-T8uduM16