gáàsì
noun
/ɡáà.sì/
Definitions
-
gas
ipò gáàsì gaseous phasegáàsì olóró poisonous gasẸ súnmọ́ mi ńbí, gbogbo ẹ̀yin idán onífèrè. Ǹjẹ́ ẹ tiẹ̀ mọ gáàsì tẹ́ ẹ máa ń fi sínú fèrè kó tó di wá di pé ẹ ń gbé e fúnra yín tẹ́ ẹ wá ń fà á símú kákàkiri? Come close, all you ballon gas inhailers. Do you even know the gas you put inside the balloons before you now come and be inhaling it everywhere?
-
natural gas; fuel gas
Wọ́n sọ wí pé púpọ̀ nínú àwọn orílẹ̀-èdè Yúróòpù ló ń gbe ìṣèjọba Russia lọ́wọ́ nípasẹ̀ ríra epo àti gáàsì Russia. They argue that multiple European countries have been enabling the Russian regime by buying Russian oil and gas.
Etymology
From English gas.
Used in
onígáàsì
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “gaasi”.
Reference:
en-gaasi-yo-noun-L-hA4TJE