fọ́
verb
Definitions
-
to break (a vessel)
bí adìẹ́ bá dà ẹ́ lóògún nú, ìwọ náà a sì fọ́ ọ lẹ́yin If a hen spills your medicine, you should break its eggs
-
to destroy (a town or nation by war)
Àwọn ọmọ ogun Ìbàdàn fọ́ ìlú Èkìtì púpọ̀ láyé àtijọ́ In the past, soldiers of the town of Ibadan destroyed many Ekiti towns
-
to become broken, to explode, to collapse
ìgò ó fọ́ yángá the bottle broke into pieces totally
-
to suffer from a headache or blindness
Ojú mi ti fọ́ I have become blindorí ń fọ́ mi I have a headache
Other entries with this spelling
Wiktionary records 5 entries spelled “fọ́”. You're reading one of them; here are the others.
Used in
Source: Wiktionary · etymology 4,
where this word is spelled “fọ”.
Reference:
en-fọ-yo-verb-JbLBqz~N