fà
verb
/fà/
Definitions
-
to pull
mo fa aṣọ I pulled the clothes
- to suck
-
to subside, to reduce
eéwó t'ó wú ti fà The boil that was swollen has reduced
-
to draw, to sketch
ó fa ìlà sórí ìwé He drew a line on the piece of paper
-
to become sluggish
ọ̀lẹ́ fà tìì lẹ́nu iṣẹ́ The lazy person was sluggish at work
-
to be elastic, to be mucilaginous (as a soup or stew), to draw
ọbẹ̀ ewédú náàá fà This ewedu soup is mucilaginous
-
to crawl
bí ìgbín fà, ìkarahun á tẹ̀lé e When the snail crawls its shell shall follow it
-
to cause, to bring about
ìyà púpọ̀ ni ó fa ẹkún Too much suffering is the cause of weeping
-
to long for
ọkàn àwọn ọmọ́ fà mí I longed for those children
Dialectal synonyms “to pull, cause” 62 varieties
Southeast Yoruba
- Ìdóàní
- fà
- Ìkàrẹ́ Àkókó (Ùkàrẹ́)
- fà
- Ìdànrè (Ùdànè, Ùdànrè)
- fà
- Ìjẹ̀bú Òde
- fà
- Ẹ̀pẹ́
- fà
- Ìkòròdú
- fà
- Ṣágámù
- fà
- Òkìtìpupa
- fà
- Mahin
- fà
- Oǹdó
- fà
- Ọ̀wọ̀ (Ọ̀ghọ̀)
- fà
- Usẹn
- fà
Ìtsẹkírì
- Ìwẹrẹ
- fà to pulllẹ̀ghẹ̀ to cause, deceive
Olùkùmi
- Ugbódù
- fà
Central Yoruba
- Àdó Èkìtì
- fà
- Àkúrẹ́
- fà
- Ọ̀tùn Èkìtì
- fà
- Ilé Ifẹ̀ (Ulé Ufẹ̀)
- fà
- Iléṣà (Uléṣà)
- fà
- Ọ̀gbàgì Àkókó
- fà
Northwest Yoruba
- Èbúté Mẹ́tà
- fà
- Abẹ́òkúta
- fà
- Ìjàká
- fà
- Èkó
- fà
- Ìbàdàn
- fà
- Igbó Òrà
- fà
- Òṣogbo (Òsogbo)
- fà
- Ìlá Ọ̀ràngún
- fà
- Ìfẹ́lódùn LGA
- fà
- Ìrẹ́pọ̀dùn LGA
- fà
- Ìsin LGA
- fà
- Ìlọrin
- fà
- Òtù
- fà
- Ìwéré Ilé
- fà
- Òkèhò
- fà
- Ìsẹ́yìn
- fà
- Ṣakí
- fà
- Tedé
- fà
- Ìgbẹ́tì
- fà
- Ọ̀yọ́
- fà
- Nàìjíríà
- fà
- Bɛ̀nɛ̀
- fà
Northeast Yoruba/Okun
- Kabba
- fà
Ede languages/Southwest Yoruba
- Sokode
- fà
- Cábɛ̀ɛ́ (Ìdàdú)
- fà
- Tchaourou
- fà
- Baàtɛ
- fà
- Igbó Ìdàácà (Dasa Zunmɛ̀)
- fà
- Ìkpòbɛ́
- fà
- Onigbolo
- fà
- Kétu
- fà
- Akpáré
- fà
- Atakpamɛ
- fà
- Boko
- fà
- Moretan
- fà
- Tchetti (Tsɛti, Cɛti)
- fà
- Aledjo-Koura
- fà
- Awotébi
- fà
- Partago
- fà
- Kandi
- fà
- Kambole
- fà
- Manigri
- fà
Source: Wiktionary · etymology 1,
where this word is spelled “fa”.
Reference:
en-fa-yo-verb-OFVmd8R8