ẹ̀rín kèékèé noun /ɛ̀.ɾĩ́ kèé kèé/
ẹ̀rín kk (alternative), ẹ̀rín kẹ̀ẹ́kẹ̀ẹ́ (alternative), ẹ̀rín kèékèékèé (alternative), erin kkk (alternative), kk (alternative)
Definitions
  1. laugh; giggle
    EYÍN rẹ ṣe pàtàkì! Wọ́n wúlò fún ọ nígbà tí o bá ń jẹun àti nígbà tí o bá ń sọ̀rọ̀, wọ́n tún kó ipa pàtàkì kan nínú ẹ̀rín músẹ́ tàbí ẹ̀rín kèékèé tí ó gún régé. YOUR teeth are important! You need them for eating and for speaking, and they are also an important part of a pleasant smile or laugh.
Other entries with this spelling
Wiktionary records 2 entries spelled “ẹ̀rín kèékèé”. You're reading one of them; here are the others.
Etymology
From ẹ̀rín (“laughter”) + kèékèé (“onomatopoeic imitation of laughter”).
Component words
ẹ̀rínlaughterkèékèéonomatopoeic imitation of laughter
Source: Wiktionary, where this word is spelled “ẹrin keekee”. Reference: en-ẹrin_keekee-yo-noun-~2aFTdJB