ejò lọ́wọ́ nínú
phrase
/ē.d͡ʒò lɔ́.wɔ́ nĩ́.nṹ/
Definitions
- a snake's hands are on its inside.
-
there's more than meets the eye; a seemingly innocent person is suspicious.
Ọ̀túnba ní ìwé àṣẹ fún irú ìbọn kan náà tí wọ́n fi pa Báyọ̀ àti Adérójú, ejò lọ́wọ́ nínú. Ọ̀túnba had the license for the same kind of gun that was used to kill Báyọ̀ and Adérójú, how suspicious.
Source: Wiktionary,
where this word is spelled “ejo lọwọ ninu”.
Reference:
en-ejo_lọwọ_ninu-yo-phrase-sN3suyqX