bẹ́ẹ̀ conj /bɛ́ɛ̀/
بعَِعَِ (alternative)
Definitions
  1. and
    Mo ní kálámù kan, bẹ́ẹ̀ náà ni mo ní ìwé mẹ́ta. I have one pen and three books
  2. even though, likewise, moreover
    Ìkùnsínú pọ̀ láàrin àwọn agbófinró; bẹ́ẹ̀, wọn kò ní agbẹ́nusọ. Complaints abound amongst law enforcement; even though that is the case, they don't have a spokesperson
Other entries with this spelling
Wiktionary records 2 entries spelled “bẹ́ẹ̀”. You're reading one of them; here are the others.
Etymology
Cognates include Ifè bɛ́ɛ̀
Used in
bẹ́ẹ̀ kọ́ bẹ́ẹ̀ niparticle àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Related terms
báyìíadv
Source: Wiktionary, where this word is spelled “bẹẹ”. Reference: en-bẹẹ-yo-conj-YgERG4Og