agbẹ́gilére noun /ā.ɡ͡bɛ́.ɡī.lé.ɾē/
Definitions
  1. woodcarver
    Bísí Fakẹ́yẹ jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká agbẹ́gilére, ó wá láti ìdílé agbẹ́gilére tí ó gbajúmọ̀. Bàbá-bàbá-bàbá rẹ̀ ni agbẹ́gilére Ọláwọyin láti Ìlá Ọ̀ràngún. Ìbátan Lámìdí Fákẹ́yẹ ni ó jẹ́. Àwọn ẹbí Fákẹ́yẹ ti gbé àwọn ìṣe àdáyébá ère gbígbẹ́ ilẹ̀ Yorùbá ga, wọn sì ti sọ ìṣe náà ti gbajúgba dé òkè òkun. Bisi Fakeye is a carver of renown, from a family of famous carvers. His great grandfather was the carver Olawoyin from Ila Orangun. He is cousin to Lamidi Fakeye. The Fakeye family have maintained and developed the carving traditions of the Yoruba people and given them international fame.
Etymology
From a- (“agent prefix”) + gbẹ́ (“to carve”) + igi (“wood”) + ní (“adverbial preposition”) + ère (“sculpture”), literally “one who carves wood into sculpture”.
Component words
Source: Wiktionary, where this word is spelled “agbẹgilere”. Reference: en-agbẹgilere-yo-noun-oEonCsDW